Tinubu fi enu tembelu awon to fe ti APC si koto
Olori Egbe Oselu APC, Asiwaju Bola Tinubu, ti bu enu ate lu awon kan to so pe won gbe opo igbese lati je ki egbe APC subu lule, ko si fo yangan.
Lasiko to n soro ni Abuja lanaa, nibi ti APC ti se ipade nla (Convention), Tinubu ni ko si ohun ti awon onibaje ati alatako ko se tan lati ma le mu erongba APC se.
O ni eemejila ototo ni won lo sile ejo pe ki won ma le ri egbe naa gbe kale, to si je pe otubante
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…