Home Orisirisi N ko je Baba Wande ni gbese Kankan – Tunde Kelani
Orisirisi - June 24, 2018

N ko je Baba Wande ni gbese Kankan – Tunde Kelani

Ti_Oluwa_Ni_Ile_cover.jpeg
Gbajugbaja onifiimu, Alagba Tunde Kelani, ti so pe ohun ti ogbontarigi osere, Karimu Adepoju, ti gbogbo aye mo si Baba Wande, so nipa oun kii se otito.
Baba Wande so ni aipe yii pe Kelani yan oun je lori fiimu TI OLUWA NILE.
O ni oun ni oun gbe oye fiimu naa jade. O ni oun ni oun ko o sile sugbon Tunde Kelani lo se e si fiimu.
O ni Kelani fun oun lowo ti o to si oun lori apa kini fiimu naa. Sugbon Baba Wande ni ko fun oun ni nnkan kan lori apa keji ati iketa.
Sugbon nigba ti Kelani n ba akoroyin Sunday Tribune soro, o ni oro ko ri bi Baba Wande se so o. Kelani ni o ya oun lenu pe Baba Wande n ba oun je ninu iwe iroyin.
O ni bi o ba tile ni ohun to n ru u loju tabi to n je e lokan, ise lo ye ki o pe oun, ki awon so o ni itunbi inubi.
Kelani ni oun fun Baba wande ni owo to to si .
Gege bi o se wi, o ni ow to to egberun lona oodunrun naira (N300,000) ni oun fun un nigba naa.
O fi kun un pe ko si ise ti oun pe Baba Wande si ti oun kii fun un ni owo, koda, o ni iye to ba so pe oun fe gba ni oun maa n fun un.
O ni eyi sele lori fiimu ABENI ati ARUGBA.
Kelani ni ohun ti ko ye Baba Wande nip e awon ajifiimuta, iyen pirates, da wahala sinu ise oun, tori gbogbo awon fiimu naa ni won ji ta.
O ni idi ti oun ko fid a Baba Wande lohun lesekese nip e oun ko fe ki abaawon tab a ile Yoruba

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…