Home Orisirisi Leyin odun kan, igbeyawo omo Adebutu pelu omo Obasanjo fo yanga-yanga
Orisirisi - June 24, 2018

Leyin odun kan, igbeyawo omo Adebutu pelu omo Obasanjo fo yanga-yanga

…iyawo Adebutu tuto soke, o foju gba a

Yoruba bo, won ni ile ola pelu iyonu.
Owe naa ti ta egbo ni ile awon ogbontarigi omo Naijiria meji, iyen Aare ana, Oloye Olusegun Obasanjo ati baba olowo Premier Loto, Oloye Adebutu Kessignton.
Ni nnkan bii odun seyin kan ni awon ebi mejeeji pe gbogbo ilu jo, nigba ti Jonwo omo Obasanjo fi Tope omo Adebutu se aya.
Igbakeji Olori orile-ede yii, Ojogbon Yemi Osinbajo, aimoye gomina, aimoye oba alaye ati awon eekan ilu miiran lo peju sibe.
Sugbon wahal nla si be sile ninu igbeyawo naa. Ile to ye ko je ile ola, ile adun ati ile oyin ti di eyi to kan gogo bayii.
Bi a se n wi yii, Jonwo ti gbe Tope lo si kootu, o ni oun ko se mo.
Esun jagidijagan lo fi n kan arabinrin naa.
Sugbon iya Tope, to je iyawo Adebutu, iyen Iyaafin Rosemary Adebutu, ti fariga. O ni iro ni won n pa mo omo oun. O ni iya Olajuwon, Iyaafin Tiwo Obasanjo ati omo re ni eku to da eyi sile tii je eda.
Teletele, Iyaafin Taiwo ko fe ki omo naa fe Tope, debi pe o gbe oro naa sile ejo nigba naa.
Gege bi Iyaafin Adebutu se so, o ni iya Jonwoimagesdc65af16ad1fcb2a85fdfe4575ae723a lo lo ogbon ayinike lati da igbeyawo naa ru.
O tun so pe Olajuwon gan-an naa ni tie lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…