Home Orisirisi Liz Anjorin soro buruku si Ronke Osodi Oke
Orisirisi - June 23, 2018

Liz Anjorin soro buruku si Ronke Osodi Oke

Ronke-Oshodi-Oke
Esu laalu onile orita, ogiri oko, si n dan mewaa wo laarin awon osere Yoruba o.
Ija to be sile laarin Mercy Aigbe ati Toyin Abraham (Aimakhu) la n so lowo, omiran tun ti gun un.
Eyi wa laarin Liz Anjorin ati Ronke Osodi Oke.
Ana ni Ronke Osodi Oke so ninu fidio kan pe kii se ohun to dara bi awon gbajumo kan se n se asehan lori ero alagbeka, ti won n tu asiri gbogbo dukia ti won ni fun araye.
Eyi lo bi Liz Anjorin ninu. Bi o tile je pe Osoi Oke ko daruko re, o ti gbe oro naa ru.
O ni ki Ronke Osodi Oke gbenu re sohun. O ni eniyan buruku ni, koda o ni atorojo agbalagba ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…