Home Orisirisi Ahmed Musa gba goolu eleekeji wole Iceland
Orisirisi - June 22, 2018

Ahmed Musa gba goolu eleekeji wole Iceland

Ahmed Musa ti wa di elewele bayii o.
O ti gba goolu eleekeji wole Iceland, ti awon ko sit ii ta putu.
Pelu bi nnkan se n lo yii, Edumare ti fi melodi si aye Naijiria.
Musa gbe awon Iceland sare bi ehoro ko to dip e o ju kinni ohun sinu awon.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…