Home LÁGBO ÀRÍYÁ Mega 99 fe gbe awo orin tuntun jade
LÁGBO ÀRÍYÁ - June 3, 2018

Mega 99 fe gbe awo orin tuntun jade

Akorin emi pelu juju – Gospel-Juju star – Abel Dosunmu tun ti fe gbe omiran yo o.
Awo orin eleekejila ni o n bo lona.
Gege bi akorin naa ti aye n gba tie lowo yii se so, akole orin naa ni APPRECIATION, to je idupe lowo Olorun ati awon eniyan to je alatilein ti ololufe re.
Akorin naa ti a mo si Mega 99 se alaye pe orin naa kun fun ogbon ati oye, bee o tun je eyi ti yoo mu inu awon eniyan dun, ti yoo si fun won ni iwuri lati jo daadaa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…