Home Orisirisi Ija nla be sile laarin Toyin Aimakhu ati Mercy Aigbe
Orisirisi - June 3, 2018

Ija nla be sile laarin Toyin Aimakhu ati Mercy Aigbe

images
Toyin Mercy lo da igbeyawo oun ru
Yomi Fabiyi soko oro si Toyin
Ija kan to be sile laarin Toyin Aimakhu ati Mercy Aigbe ti n tan kaakiri ni kiakia o.
Toyin, eni ti o ti di Toyin Abrahama bayii, lo gbe aawo naa sita, nigba to pe Mercy ni alabosi, alabomooru. Koda, lori ero alagbeka Instagram, o ni Mercy ni modaru to da igbeyawo oun ru.
Bi o tile je pe eni oro kan ko tii soro, osere fiimu miiran ti a mo si Yoi Fabiyi ti so pe ki Toyin gbe enu re soun.
O ni iwa buruku wa lowo re, lo fi je pe o fe maa n fi ohun ti ko dara sere.
Yomi so eyi nipa bi Toyin se soro pad ape lilali ti oun laali Mercy, oun kan fi n sere ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…