Home Orisirisi Ibon Ekiti: Ta lo fe se’ku pa Opeyemi Bamidele ati Fayemi?
Orisirisi - June 3, 2018

Ibon Ekiti: Ta lo fe se’ku pa Opeyemi Bamidele ati Fayemi?

Awon agbofinro ko si tii mo odo ti won o dorunla si lori bi olopaa kan se doju ibon ko awon agbaagba oloselu APC ti Ekiti lojo Jimoo.
Ibon naa ba Alagba Opeyemi Bamidele ati awon eniyan bii meta miiran, to si je pe digbadigba ni won ru Bamidele lo si osibitu.
Ibi oro ti koko ruju nip e won ni Eko lo ye ki olopaa naa wa nibi ti o ti n sise, ki eni kan to tii lopon-pon-on lo si Ekiti.
Ara ibeere ti awon agbofinro n bi ara won bayii nip e: Se atilaawi moomo fe pa Fayemi ati Bamidele ni abi o seesi ni? Se egbe PDP lo ran an nise ni? Se awon kan tinu n bi ni APC ni? Abi awon ti a ko tie mo ni – boya okunrin naa si mu igbo ati paya yo ni?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…