Home Orisirisi Genrot Rohr ko ni mu ‘Mikel’ lo si World Cup
Orisirisi - June 3, 2018

Genrot Rohr ko ni mu ‘Mikel’ lo si World Cup

eagg
Adari egbe agbaboolu Super Eagles, ti gbe oruko awon agbaboolu metalelogun (23) to n ko lo si Russia fun idije fun ife eye agbaye – World Cup.
Awon meedogbon (25) lo ti n ko sodi tele, sugbon o ti ja meji sile bayii.
Awon meji naa ni Ola Aina ati Mikel Agu. Sugbon Mikel agba, iyen Mikel Obi n lo si Russia pelu Super Eagles.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…