Home Orisirisi MC Oluomo ati Pasuma jere nla nla nilu oyinbo
Orisirisi - May 31, 2018

MC Oluomo ati Pasuma jere nla nla nilu oyinbo

omopaso
… Omo won kawe gboye ni Amerika
Iroyin ayo lo n jade lera won lowolowo yii, ti o si je pe adura ni a o maa gba ki a tubo maa gbo iru re.
Ekinni ni ti awon ibeji gbajugbaja oga awon onimoto, MC Oluomo, ti won sese pari eko won ni University of Atlanta ni Georgia.
Pelu idunnu ni MC Oluomo fi lo baa won omo naa, pelu awon molebi ati ololufe re.
Se eni ti a ro pe ko le pago ni oro MC Oluomo, to wa n kole alarinrin.
Bakan naa, orin Aliamudulilai ni gbankogbi fuji, Wasiu Alabi Pasuma, n ko lowo yii, latari bi omodebinrin re, Opeyemi Khadijat, se pari eko re, to si se ayeye asejade ti a mo si convocation ni University of Atlanta bakan naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…