Home Orisirisi Fanikayode ko gba penalty wo throw-ing!
Orisirisi - May 31, 2018

Fanikayode ko gba penalty wo throw-ing!

Pelu idan orita ti oloselu ti a mo si Femi Fanikayode, pa lose to lo, o ti fihan pe oun ko setan lati se bi awon ti akorin Small Doctor n ba wi.
O se ise akoni nipa gbigba boolu sinu awon iyawo re, Precious.
Fanikayode ko si gba ‘penariti wo throw in’ bi orin Small Doctor.
Dipo bee, ami ayo meta ototo lo gba wole Precious, ti oun naa si bi omokunrin meta lanti-lanti fun un ni ose to lo.
Ki Olorun da awon omo naa si, ki Edumare si je ki a tubo maa gbo iroyin idunnu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…