Home Orisirisi Bayii ti Gani Adams ti kawe gboye ni LASU…
Orisirisi - May 31, 2018

Bayii ti Gani Adams ti kawe gboye ni LASU…

download
Nigba kan ri, bi won ba daruko OPC, oro ada ati ibon lo maa n o sokan opo eniyan. Sugbon itoo ti so omiran, alabahun ti kuro ni iye ti a n ra a.
Eyi lo difa fun olori ijo naa, to tun wa je Aare Ona Kakanfo Yoruba, Otunba Gani Adams, to si fila Aare sile si egbe kan lojo Alaaruba, to si de fila oye imo ijinle to sese pari.
Ni pataki, Gani Adams wa lara awon ti won sese kawe gboye ni Lagos State University ni Ojo. Opo awon omo egbe OPC ati ololufe Gani ni won pejo sibi ayeye naa.
Ni pataki, a ni lati ranti pe nigba ti Alaafin fe fi Gani Adams je oye Aare Ona Kakanfo, awon kan n fenu tembelu re pe kafinta lasn ni won fe fi joye – awon ti won ti gbagbe pe kafinta ni baba Jesu!
Bayii ti o ti wa kawe gba Bachelor of Arts yii, kin ni won tun fe so o?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…