Home LÁGBO ÀRÍYÁ Linda Ikeji so fun Charly Boy pe oun maa se igbeyawo
LÁGBO ÀRÍYÁ - May 22, 2018

Linda Ikeji so fun Charly Boy pe oun maa se igbeyawo

image-53
Oludasile lindaikejiblog, Linda Ikeji, eni to sese so fun araye pe oun ti finu soyun, ti tun fi oba le e o.
O ti fi da awon ololufe re loju pe ibukun ti Olorun fun oun kii se oyun nikan.
Nigba ti kiigbo-kiigba akorin ti a mo si Charly Boy ba a dupe lori bi oyun se de, ni o dara bee, bi ko se sese maa sopo se igbeyawo.
Sugbon Linda mu u da Charly Boy loju pe oun maa se igbeyawo, ti oun yoo si fie yin gbomo pon, leyii to tumo si pe eni to loyun fun ti setan ati fi oruka si i lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…