Home Orisirisi Iro ni won pa pe mo maa n sa ni kilaasi – Odunlade Adekola
Orisirisi - May 20, 2018

Iro ni won pa pe mo maa n sa ni kilaasi – Odunlade Adekola

Gbajumo osere fiimu, Odunlade Adekola, ti so pe oun se bi o ti to ati bi o se ye nigba ti oun n kekoo gboye ni ile iwe giga ti University of Lagos.
Odunlade sese pari ni UNILAG ni, ti inu re si dun pe ninu ofii, ninu olaa ni omo pandoro gbo si.
O ni bi o tile je pe ko rorun fun oun, oun ko fi igba kan sa ni kilaasi.
O ni oun gbajumo eko oun, ti awon akegbe oun si le jeri sii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…