Home Èfè ati Àwàdà Idi ti oko iyawo fi n lo yeti
Èfè ati Àwàdà - April 30, 2018

Idi ti oko iyawo fi n lo yeti

Okunrin kan ni awon ore re bii leere igba ti oge ta le lara ti o bere si ni lo yeti. O ni lati igba ti iyawo oun ti ka yeti mo inu moto oun ni oun ti so ibaje di ewa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…