Home Orisirisi Emi o le ku o – Guru Maharaji
Orisirisi - April 30, 2018

Emi o le ku o – Guru Maharaji

Iroyin tan kaakiri ni aipe yii pe gbaju-gbaja okunrin kan to pe ara re ni omo Olorun ti iku ko lee pa, ni okiki re tan ka gbogbo Naijiri a pe o ti je ipe Olorun. Gbogbo awon ero alagbeka igbalode lo gbee pe baba naa ti salaisi.
Iroyin miran tun wa gbee pelu opolopo iwadii pe baba naa ko ku. Won ni igba ti oun naa ka nipa iku ara re, oun rerin pe, opo ko tile mo eni ti won n pe ni SAT GURU Maraji. O ni eedegbeta odun lonii, oun si maa wa lorile aye yi.
Awon iroyin miran tun gbee pe “iko fee” lo pa baba naa. Won ni aisan iko tii n see to ojo meloo kan ki o to wa muu lo patapata. Sat Guru Maharaji ni, ko si ohun to se oun, saka ni ara da.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…