Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Asise koosi Klopp da ijaya sile fun Liverpool (5-2)
ERÉ ÌDÁRAYÁ - April 24, 2018

Asise koosi Klopp da ijaya sile fun Liverpool (5-2)

Bi o tile je pe Liverpool bori ninu idije re pelu Roma, ninu semi final Champions League to waye lale oni, pelu ipaya ni won fi pari re.
Bee, inu ipaya ni awon ololufe won kaakiri agbaye wa bayii.
Ami ayo marun-un ni Liverpool ni, ti Roma si ni meji.
Pelu ofin idije naa, ami ayo meji ti Roma ni tumo si meta, tori ile Liverpool ni won ti gba boolu naa.
Ti a ba wa wo itu ti Roma pa fun Barcelona, to da ami ayo bii meta pada, a o ri i pe o seese ki o gba ami ayo meta sile Liverpool nigba ti awon naa ba lo ba Roma nile.
Liverpool lo koko gba ami ayo maraarun wole Roma, ti awon naa si da meji pada.
Igba ti adari Liverpool, Jurgen Klopp, yo Salah ni o jo pe nnkan ti fe daru fun won.
Koda, awon omoran ni asise nla ni eyi je.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…