Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ 2019: Babangida ati Obasanjo n se afeyinti fun egbe SDP
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - April 17, 2018

2019: Babangida ati Obasanjo n se afeyinti fun egbe SDP

O seese ki Oloye Olusegun Obasanjo ati Ogagun Ibrahim Babangida se atileyin fun egbe Social Democratic Party ti Oloye Olu Falae da sile o, fun idibo 2019.
Obasanjo ati Babangida ti koyin si Buhari, ti won si so pe ki o ma gbe apoti mo.
Sugbon Buhari naa fihan pe bi awon mejeeji se soja ni oun naa je ologun. O ti so pe oun si fe gbe apoti leekan sii.
Babangida ati Obasanjo ti gba Falae lalejo lokookan ni Minna ati Abeokuta, ti won si foju rere wo SDP.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…