Home iroyin Ko si ibo oni komputa ni odun 2019 – INEC
iroyin - April 15, 2018

Ko si ibo oni komputa ni odun 2019 – INEC

Ojogbon Mammod Yakubu ni o n ba awon oniroyin soro ni ilu Abuja pe ko le si idibo onina pelu ero komputa gege bi ero ajo naa tele fun idibo odun 2019.
O ni riro ni ti eniyan, sise ni ti Olorun Oba. O ni gbogbo igbiyanju ajo INEC lori ati lo eto idibo tuntun lo ja si pabo pelu awon ipenija kookan. O ni awon ko si fe ki eto idibo naa ni konu-n-koo ninu rara.
Eyi lo si je ki awon tete pokan po si eto idibo ti a ti n lo tele, ti gbogbo eniyan mo kika re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…