Home iroyin Awon akekoobinrin Chibok ati Dapchi ti pe ju lowo Boko Haram – Tunde Bakare
iroyin - April 15, 2018

Awon akekoobinrin Chibok ati Dapchi ti pe ju lowo Boko Haram – Tunde Bakare

Ojise Olorun, Tunde Bakare ni gbogbo agbara ati ete ti ijoba apapo ba mo ni ki won lo lati gba awon akekoobinrin Chibok ati Dapchi kuro lowo awon Boko Haram.
O ni opo awon omo olomo yii lo ti wa ni sakani awon eniyan buruku yii lati odun merin seyin. O ni itiju ati abuku nla pata-pata ni eleyii. Bakare n salaye yii nibi idanilekoo kan to lo se ni ilu Abuja.
Ojise Olorun yii ni gbogbo eto ni awon omo naa ni lati maa gbe igbe aye alaafia gege bi omo orileede yii. O ni ijoba apapo ti te ofin ati eto awon omo naa mole nipa wiwa ni ibi ti won ko fe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…