Home Orisirisi Olubadamoran Adebayo Shittu ni minisita je gbese owo aso
Orisirisi - April 14, 2018

Olubadamoran Adebayo Shittu ni minisita je gbese owo aso

Leyin bii osu kan ti okan lara awon olubadamoran Minisita fun oro Ibanisoro, Alhaji Adebayo Shittu, kowe fi ipo sile, eni miran to je olubadamoran Shittu tun ti kuro lodo re o.
Ohun to wa le ninu eleyii nip e, pelu ibinu ni o fi n so awon nnkan asiri ti o so pe o wa ninu aye minisita naa.
Ninu atejade nla kan lonii, olubadamoran naa, Sheikh Tajudeen Imam, so pe Shittu hu awon iwa kan ti ko to pelu arabinrin kan.
O tun so pe minisita naa je awon kan I gbese owo aso ni Abuja.
Lori Facebook ti Imam gbe oro naa si, opo eniyan kan n ko ‘Haa’ ni. Nigba ti awon kan n bu minisita naa, awon eniyan kan n so pe o seese ki oro naa ma je otito, won ni boya ija lo de ti orin di owe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…