Home Orisirisi Ole buruku to ja ni Ofa: Iwonyi ni oruko awon eniyan mejila ti awon olopa ti gbamu
Orisirisi - April 13, 2018

Ole buruku to ja ni Ofa: Iwonyi ni oruko awon eniyan mejila ti awon olopa ti gbamu

Olu ile olopaa Naijiria ti se atejade awon eniyan mejila ti won ti gbamu, latari pe won fura sip e won lowo ninu ole to ja ni ilu Ofa lose to lo, nibi ti won ti pa opo eniyan.
Alukoro awon olopaa, Alagba Jimo Moshood lo se atejade naa.
Awon oruko naa, ati ibi ti won ti gba won mu ni:

i) Adegoke Shogo 29yrs – Arrested in Offa

ii) Kayode Opadokun 35yrs – Arrested in Offa

iii) Kazeem Abdulrasheed 36yrs – Arrested in Offa

iv) Azeez Abdullahi 27yrs – Arrested in Offa

v) Alexander Reuben 39yrs – Arrested on the 11th April, 2018 in Lagos

vi) Jimoh Isa 28yrs – Arrested on the 11th April, 2018 in Lagos

vii) Azeez Salawudeen 20yrs – Arrested in Offa and victim’s phone and sim cards recovered from him

viii) Adewale Popoola 22yrs – Arrested in Offa and victim’s phone and sim cards recovered from him

ix) Adetoyese Muftau 23yrs – Arrested in Ibadan, Oyo State

x) Aminu Ibrahim 18yrs – Arrested in Ilorin

xi) Richard Buba Terry 23yrs – Arrested in Ilorin

xii) Peter Jaba Kuunfa 25yrs – Arrested in Ilorin

Ibosi o! Awon ajinigbe ji ibeji Otun Olubadan gbe
Ibi oro aao Naijiria de lonii, afi ki Olorun o gbakoso ni o.
Idi ni pe ojoojumo ni awon janduku n da bira.
Ni bayii, won ti ko Otun Olubadan, aOba Lekan Balogun, ati awon ebi re sinu paahee, nipa wiwole gbe ibeji re to je omo odun marun-n lo.
Ise ni awon ajinigbe naa ya wo ile re to wa ni Akobo ni Ibadan, ti won si koju ogun si awon ara ile. Bee ni won se gbe awon ibeji naa salo.
Won ti wa so pe Otun Olubadan gbodo gbe ogorun milionu naira (N100m) sile ti o ba fe gba awon omo re pada.
Awon olopaa IPinle Oyo ti so pe otito ni isele naa sele.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…