Home Orisirisi Eemo wolu, ROMA le BARCELONA danu ni CHAMPIONS LEAGUE
Orisirisi - April 10, 2018

Eemo wolu, ROMA le BARCELONA danu ni CHAMPIONS LEAGUE

Lionel+Messi+Roma+v+FC+Barcelona+UEFA+Champions+thMO5WF0uTkl
Ajalu buruku de ba egbe agbaboolu Barcelona ni ale oni, nigba ti egbe agbaboolu Roma le won danu ninu idije Champions League ti odun yii.
Roma gba ami ayo meta otooto wole Barcelona nigba ti awon ko si le ta putu.
Ohun ti o fi ya opo eniyan lenu ni pe ami ayo merin otooto ni Barcelona ni nile tele, ti Roma si ni okan nigba ti won koko pade ni ile Barca.
Eyi je ki opo eniyan gba pe Barca yoo tun na Roma ni anapa mokuu.
Sugbon oro ko ri bee mo.
Messi gan-an, to je oba soccer, ko ri goolu eyo kan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…