Home iroyin Owo olopaa pada te Osama
iroyin - April 2, 2018

Owo olopaa pada te Osama

Ogbologbo afunrasi Kabiru Sheidu ti alaje re n je “Osama”to ni seneto Dino Melaye lo ran oun ati awon janduku kan lati maa da ipinle Kogi ru, to di ojo to ye ko fara han nile ejo naa ni oun ati awon marun-un miran na papa bora ni owo awon olopaa ti pada te bayii.
Ago olopaa to wa ni ilu Abuja ni won ko gbogbo awon ti won sa mo awon olopaa lowo ni Lokoja lo fun aabo to daju.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…