Home Orisirisi Buhari se’daro Winne Mandela
Orisirisi - April 2, 2018

Buhari se’daro Winne Mandela

Aare Mohammadu Buhari darapo pelu awon eniyan to ku ni agbaaye lati sedaro iku iyawo Aare tele ri ni orileede South Africa, arabinrin Winne Mandela. Mama yi ti wa lori aisan fun igba die, bi o se n wo ile iwosan ni o n jade, ki iku to pa oju re de ni osan oni ni ile iwosan Johannesburg.
Winne ku ni omo odun mokanlelogorin (81years). Ki Eledua ba wa te mama naa si afefe rere.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…