Home Orisirisi D’Banj si ile tuntun, Wizkid n fi moto nla nla yangan
Orisirisi - March 20, 2018

D’Banj si ile tuntun, Wizkid n fi moto nla nla yangan

D-banj
Aye oloba si n lo repete laarin awon alariya Naijiria, bi awon olorin meji kan se gbe ogo Olorun jade lose to lo.
Se omaale ni owo, kii se e gbe pamo mo nigba ti o ba tip o goboi.
Awon olorin naa ni D’Banj ati Wizkid.
Nigba ti D’banj sese si ile nla kan ni Ikoyi, adugbo awon olowo ni ilu Eko, Wizkid naa ko awon moto bembe bembe kan jade bii omo ojo mejo.
Lara awon moto naa ni G Wagon ati Bentley, to je pe opo milioni naira ni won fir a won.
Bi a ko ba gbagbe, awon alariya omo Yoruba bii Funke Akindele, Omotola Jalade Ekehinde, Alao Malaika, Kunle Afolayan, Wasiu Ayinde, Saheed Osupa, Pasuma ati Alao Malaika ti si ile tuntun nla nla.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…