Home LÁGBO ÀRÍYÁ Araye se iranti Duro Ladipo pelu ere AJAGUNLA
LÁGBO ÀRÍYÁ - March 20, 2018

Araye se iranti Duro Ladipo pelu ere AJAGUNLA

O ti di ogoji odun gbako bayii ti osere pataki, Duro Ladipo, peyin da.
Awon ebi, ololufe ati agbasaga wa n se iranti re lowolowo yii pelu ere onise kan ti won pe akole re ni Ajagunla.
Omowe pataki kan, Ojogbon Rasak Ojo-Bakare, lo dari ere naa, nigba ti okan lara awon omo oloogbe se agbateru re.
Ijoba Ipinle Eko ati ibugbe asa Centre for for Black Culture and International Understanding to wa ni Osogbo wa lara awon to ran awon osere naa lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…