Home Orisirisi Ade Lawyer: Ogbologbo odaran di atunbi leyin to pa ogorun eniyan
Orisirisi - March 20, 2018

Ade Lawyer: Ogbologbo odaran di atunbi leyin to pa ogorun eniyan

Olohunwa
Ase ooto ni Olorun wa leyin Olohunwa!

Okunrin ogbologbo odaran kan ti se alaye itu ti oun ti pa paapaa ni Ipinle Eko o. O ni lenu ise alagbapa ti oun yan laayo, o le ni ogorun eniyan ti oun ti pa.
Oun naa ni Adeola Williams, ti inagije re n je Ade Lawyer.
Panpe awon olopaa ni Ade Lawyer wa, to wa n ka boroboro.
Nigba ti won koko mu u, o ni okan ninu awon olori onimoto, Alagba Olohunwa, lo ran oun ni ise iku si Oga Onimoto miiran, Kunle Poly. Ori iya Kunle Poly yo o, tori amugbalegbee re, Ganiyu Ayinla ni Ade Lawyer ri pa.
Awon olopaa koko mu Olohunwa naa, sugbon won ti fi sile.
Ohun to se pataki julo nip e Ade Lawyer ti so pe Olohunwa ko ran oun nise. O ni oun kan paro mo o ni tori ko setoju oun daadaa mo.
Adeyer, eni to je omo Ijebu Igbo, ni oun ti di atunbi bayii, ki ijoba boju aanu wo oun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…