Home Orisirisi Enoch Adeboye ro ijoba apapo ko dawo itajesile duro
Orisirisi - March 16, 2018

Enoch Adeboye ro ijoba apapo ko dawo itajesile duro

Oludari agba fun ijo Redeemed, G O Enoch Adeboye ti olu-ile ijosin re wa ni opopona masose Eko si Ibadan, se abewo si ipinle Benue lartari opo emi to sonu nibi ija awon Fulani darandaran.
Baba Adeboye mu iyawo won, baba ni ko si ojise Olorun tooto to maa gbo pe won sin oku opo eniyan ti ko ni ba inu je. O ni awon ijo Redeemed ba awon ara ipinle Benue sun ekun nigba ti won n sun ekun nitori pe eleran ara ni awon naa.
Olori ijo naa wa gba ijoba apapo nimoran pe ki won lo gbogbo agbara ti o wa ni ikawo won lati dawo itajesile duro ni orileede yii.
Samuel Ortom tii se gomina ipinle Benue fi emi imoore han ki alagba naa to lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…