Paul PSquare fi eni to fe lu u ni jibiti se yeye
Die lo ku ki okan lara awon ibeji akorin PSQuare, Paul Okoye, lu takute gbajue kan lose to lo.
Eni ibi naa paro pe oun ni Emir ti ilu Kano, Emir Lamiso Sanusi.
Ibi ti o ti n ba PSquare tayo olopon lori ero alagbata ni o ti ni ki o fi milionu marun-un naira ranse si oun, tori pe wahala kan wa lori aka-n-ti oun ni banki.
Bayii ni Paul Okoye se mo pe omo Yahoo Yahoo ni okunrin naa.
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…