Home iroyin Oko iresi ilu Kebbi mu inu Lai Mohammed dun
iroyin - March 12, 2018

Oko iresi ilu Kebbi mu inu Lai Mohammed dun

Minisita fun eto iroyin ati asa ni orileede yii, Alhaji Lai Mohammed lo fi idunnu re han si gomina ati awon eniyan ipinle Kebbi fun akitiyan won nipa ogbin iresi. O ni pelu opo yanturu oko iresi yii to lati fi awon ara ilu lokan bale pe, iresi ati awon ohun ogbin ti awon eniyan mura si yii maa fa opo oriire wo ilu.
O ni,eyi koko maa din oda ounje ku pelu igbagbo Yoruba to ni “ti ebi ba ti kuro ninu ise, ise bu se”. O ni iresi yii tun maa to lati ta si ile okeere ti o si maa mu owo goboi wa fun orileeede.
Lai Mohammed wa gba awon ipinle to ku ni iyanju lati di awon nnkan gidi mu lati fi ran awon ara ilu lowo ati orileede lapapo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…