Customs gba moto to le ni Bilionu naira ni Lekki
Awon eso asobode (Customs) ni won ti gbese le awon oko olowo iyebiye ti owo re le ni Bilionu naira. Awon oko igbalode naa ni – Rolls Royce, Chryler, Audi Q7, Land Rover HSE, Toyota Venza, Ford Taurus, Honda Cross tour, Mercedes Benz, Kia Rio, Escalade ati bee bee lo.
Gege bi Mohammed Uba to je oga awon eso oju ona Zone A, Ikeja se salaye fun awon oniroyin ni ojo kinni, osu keta odun yii. Oga Customs naa salaye pe eni to n ta moto naa ko lati tele ofin ijoba apapo lo je ki awon lo gbese le awon oko naa.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…