Nnkan ko rorun fun awa gbajumo – Foluke Daramola
Osere fiimu ti a mo si Foluke Daramola ti so pe bi o tile je pe awon gbajumo maa n dan loju ni ita, nnkan ko ri bee fun awon ninu ile.
O ni onikaluku lo mo ohun to bo mo abe aso, ati ohun to n bawon finra labe oode.
O so oro yii nigba to n ro arojinle lori ayeye ojo ibi ogoji odun re.
O ni opo eniyan lo maa n ro pe ohun to n dan ni dingi, sugbon oro ko ri bee.
O wa fi kun un pe asiko ti igbeyawo oun akoko daru ni nnkan le fun oun ju.
O ni sugbon bayii, oun n je mudunmudun igbeyawo nile ayanfe Olorun ti oun wa.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…