Home iroyin Ija egbe APC ti n ba ona ibomiran lo ni ilu Kaduna
iroyin - February 22, 2018

Ija egbe APC ti n ba ona ibomiran lo ni ilu Kaduna

Ojo aje, ojo kejidinlogun, osu keji yii ni awon kan dede ni awon yo gomina ipinle Kaduna, Nasiru El Rufai ni egbe fun osu mefa nitori pe ko tele alaale egbe naa. Aigbora-eni ye si ti n waye lera-lera laarin gomina naa ati Seneto Sani ni ipinle naa.
Oro naa dabi ere tabi awada, ni ojo keji nigba ti awon abala kan ti ko fara mo gomina dede ba ile egbe won to ti dawo. Awon ara adugbo naa ni gomina lo ran awon osise re wa pelu katapla lati wa da ile naa wo. Titi di asiko ti a n ko iroyin yii jo, ko tii si oniroyin to gbo abala ti gomina naa rara.
Awon Seneto ile wa si ti fariga pe nnkan buruku ni gomina se ti o ba lo je pe oun ni o ran won lati lo da ile naa wo. Awon ara adugbo naa ni awon moto merin to kun fun awon olopaa ati Soja ni won tele katapila naa wa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…