Ibon ko gbodo wo Naijiria mo – IGP
Oga patapata awon olopaa ti paa lase fun gbogbo awon komisona olopaa ni Naijiria pe ibon kankan ko gbodo wo ipinle won mo lati oni ojo kejilelogun, osu keji nitori wahala ti po ju bayii ni orileede yii.
O ni ti ifowo-sowo po yii ba waye, o maa din jagidijagan ku ni orileede yii. O ni ayewo to muna doko gbodo wa fun gbogbo moto to ba n wole ati eyi to n jade nitori awon onise ibi naa.
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…