Home iroyin Fayose pin aga ijokoo fun awon akekoo ni ipinle Ekiti
iroyin - February 22, 2018

Fayose pin aga ijokoo fun awon akekoo ni ipinle Ekiti

Gomina ipinle Ekiti, alagba Ayodele Fayose ni o bere si ni pin aga ijokoo ati tabili fun awon ile-iwe ijoba ti ko si aga ijokoo to kari won mo. O si se ileri pe oun sese n mu eye bo lapo ni.
Fayose tun wa be awon oluko ati awon alamojuto eto eko ni ipinle naa lati foju to awon aga naa, nitori pe arun buruku kan ba awa eniyan dudu je. Ti nnkan ti ijoba ba fowo se ba baje, gbogbo wa ni a maa n woo niran pe “nnkan ijoba ni”.
Gomina ni ki awon alamojuto jowo ma se je ki o ri bee nitori awon omo yii ni o maa je iya to po ju ti awon nnkan naa ba tete baje. O si tun se ileri pe oun ko ni je ki iya Kankan to si awon omo naa ati awon oluko won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…