Home iroyin Awon akekoo aadota sonu sowo awon ajinigbe
iroyin - February 22, 2018

Awon akekoo aadota sonu sowo awon ajinigbe

Wahala awon akekoobinrin Chibok ko tii pari lati bii odun merin seyin, awon akekoo to le ni igba ni awon eni ibi yii ko ti won si bere si ni fi won sile diedie. Pelu gbogbo ogbon ati ete, awon eniyan buruku yii ko tii fi gbogbo omo sile.
Bayii, awon akekoo bii aadota ni won tun ji ko ni ile-iwe awon obinrin Dapchi, to wa ni ipinle Yobe. Awon die sa mo won lowo ni igba ti moto won baje ni ona. Eyi ni ko ni je ki a le so iye omo to wa ni akata won bayii. Oga ile-iwe naa ni igba ti won ka omo ni awon to mo pe awon akekoo awon din aadota. O ni omo merindinlogbon le leedegberun (926) lo ye ki awon omo naa je.
Akekoo to ja ajabo lowo awon eni ibi yii lo n salaye fun awon oniroyin ni ilu Yobe. Omi n be lamu fun ijoba yii. Awon eniyan buruku ti po ju ni orileede yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…