Atunse kaadi idibo maa waye ni ipinle Kano – INEC
Oga patapata fun ajo eleto idibo INEC Mahmood Yakubu ti se ileri pe ki egbe oselu PDP ati awon egbe to ku ma se mikan. O ni gbogbo fidio bi awon omode ti ko tii lojo ibo didi lori se n foruko sile ni o ti kan oun lowo.
O se ileri pe ajo INEC gbodo tun foju awon asebi ati odale ti won n foju ofin gbole jofin. O ni iwa buruku gbaa ni iru iwa naa. O ni ajo awon ati awon agbofinro maa sise lori re.
Ana ojo isegun ni ogbeni Kola Ologbondiya n ba awon oniroyin soro nipa iwa ibaje ati jibiti ti ajo INEC wu ni ipinle Kano ati Katsina. Oni ojo’ru ni awon awon ajo INEC ti sare dahun, ki awon ara ilu baa le ni igbekele ninu won.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…