Home Orisirisi Araye gboriyin fun Ambode lori ipinnu re lori idagbasoke ede Yoruba
Orisirisi - February 21, 2018

Araye gboriyin fun Ambode lori ipinnu re lori idagbasoke ede Yoruba

Awon asofin APC fo’wo si ki gomina gbapoti leekeji

Awon asofin Egbe APC ti won wa ni ile asofin ni Abuja ti fi owo si ki Gomina Akinwunmi Ambode gbe tun soju egbe naa ninu idibo gomina to n bo ni 2019.
Won se eyi ni Eko lojo Satide, nigba ti won se abewo si gomina nile ise ijoba.
Won ni Ambode ti sise takuntakun, ti inu awon ara ilu I dun si i.
Bakan naa, opo eniyan lo ti gboriyin fun Ambode lori bi ijoba re se gbe igbese lori itesiwaju ede Yoruba.
Ambode ti pa a lase pe o tip on dandan ki awon omo ile iwe paasi Ede Yoruba ki won to le wo yunifasiti ni Ipnle Eko.
Eyi tumo si pe dandan ni ki gbogbo ile iwe maa ko eko ede naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…