Home LÁGBO ÀRÍYÁ Dokita lo pa mi lomo – Eucharia Anunobi
LÁGBO ÀRÍYÁ - February 20, 2018

Dokita lo pa mi lomo – Eucharia Anunobi

Osere fiimu pataki to di pasoto, Echaria Anunobi, ti so pe iku omo oun ni odun to koja kii se amuwa Olorun.
O ni dipo bee, doikta to n toju omo naa lo se asise ti o fi ran omo re kan soso si orun aremobo.
Eucharia so oro yii lasiko to n se ayajo ojo ibi omo naa.
Odun yii ni Raymond kiba di eni odun merindinlogun.
Eucharia ko so hulehule bi doikta naa se pa a, sugbon o ni nigba ti Raymond ba wa laye, awon maa n se ojo ibi re nipa lilo fun awon omo alaini ati alainiyaa ni ebun.
Bakan naa ni iya omo naa se lati sami ojo ibi re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi

Ọwọ́ pálábá adigunjalè ẹlẹ́nimẹ́ta tó ja Tọpẹ Alabi lólè owó ṣégi Ọrẹ Òtítọ́jù Ọjọ́ gbogbo…