Alabi Pasuma n mura sile fun oselu
Akorin fuji pataki, Wasiu Alabi Pasuma, ni nnkan kan to yato si orin lokan bayii.
O jo pe oun naa fe se oselu.
Ohun to kan wa yani lenu ni pe ko fe duro legbe jegede, ise lo fey an eko nibi ayo gbe ga.
O so lori ero alatagba Instagram re pe pun fe diije fun ipo aare.
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…