Home Orisirisi O se, iya Olamide di oloogbe
Orisirisi - January 30, 2018

O se, iya Olamide di oloogbe

Lonii ti gbajugbaja akorin hiphop, Olamide, n se ajoyo ojo ibi omo re, nnkan nla jabata kan ti sele ninu aye re.
Iya to bi i ninu ti di oloogbe.
Pelu edun okan ni Olamide fi so lori ero alatagba pe igi ti da, to si tenu mo o pe ‘Oria bi iya ko I.’
A gbo pea are ti n se iya naa fun bii igba kan ki olojo to de.
Pelu iku iya naa, Olamide ti di omo orukan, tori baba re ti ku tele.
Omo mefa ni oloogbe naa fi saye lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Wọ́n ti taari Sunday Igboho sílé-ẹjọ́ ní Kotonú

Wọ́n ti taari Sunday Igboho sílé-ẹjọ́ ní Kotonú Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà ní bí ọ̀rọ̀ nlá k…