Home ÀṢÀ ÀTI ÌṢE Ọba Ọlasunkanmi Tijani (Alawowo ti ilu Awowo) fi ọjọ́-ìbí rẹ̀ sàánú ará ìlú
ÀṢÀ ÀTI ÌṢE - iroyin - January 8, 2018

Ọba Ọlasunkanmi Tijani (Alawowo ti ilu Awowo) fi ọjọ́-ìbí rẹ̀ sàánú ará ìlú

Bi owon gogo epo pentiro se gbode kan to ni ojo kerinlelogun (24 th ) Osu
Kejila, Odun 2017 ti idunnu atayo ni awon oninuure, ore ati awon omo
bibi Ilu Awowo ni Ijoba Ibile Ewekoro ni Ipinle Ogun se tuyaya-tuyaya si
gbagede ajoyo ojo ibi Oba Abdul Gafar Olasunkanmi Tijani (Alawowo Ti
Ilu Awowo) fun ayeye odunkejidinlogota ti won ti wa lori okeeepe nipa
oore ofe ati abo to daju gege bi Oba lati odo Allah. Nipa sise eyi,
Alayeluwa nawo ife si awon akekoo ile-eko Ilu Awowo, ohun amaye-
derun lolokan-o- jokan fun awon ara ilu ati fifi oye da awon eniyan
Pataki lola lawujo. Lara awon ti Kabiesi fi oye da lola ni awon obinrin bii
okunrin ninu iselu Orileede Naijeria paapaa julo ni Ipinle Eko, Alaga
LCDA ti ilu Amuwo Odofin Hon. Ogabi Aderonke Mary JP gege bi Yeye
Jagunmolu ati Alaga LCDA ti Oriade Ramotalai Akinlola Hassan gege bi
Gbadega ti Ilu Awowo ati agbegbee re. Lara awon Oriade to ba Kabiyesi
sajoyo ni: Elejio ti ilu Ejio Oba Ogunmuyiwa, Olorile ti Orile Ifo ati awon
Oba miiran bee ni Hon. Egunjobi ati awon eniyan pataki ninu oselu ko
gbeyin. IROYIN OWURO naa ko rose rara lati ba Alayelua sajoyo ojo ibi
won pelu awon aworan lolokan-o- jokan:

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Kò sí nǹkan tó ṣòro tó kí ènìyàn pàdánù ọkọ….. Bimbo Oshin

Kò sí nǹkan tó ṣòro tó kí ènìyàn pàdánù ọkọ….. Bimbo Oshin Ọrẹ Òtítọ́jù Iná ọkọ,aya …