Home LÁGBO ÀRÍYÁ Oro ife bi adanwo: Saidi Balogun fi owo mo Fathia lori
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - January 2, 2018

Oro ife bi adanwo: Saidi Balogun fi owo mo Fathia lori

Oro ife bi adanwo ni loooto. Leyin bii odun mewaa ti igbeyawo Saidi Balogun ati Fathia Blogun ti daru, okunrin naa se nnkan iyanu kan lojo Monday.
Nibi ojo ibi osere fiimu Mercy Aigbe, ori Saidi dide janin nigba ti Fathia n jo, o sig be bondu owo jade, to sib ere sii le naira mo iya awon omo re naa lori.
Ibe ni ariwo ti ta gee, ti awon to wa nibe n patewo.
Ija loko-laya naa le debi pe Saidi ni ki Fathia gbe oruko baba oun ju sile, leyii to fa a ti obiinrin naa fi pada n je oruko ti baba re naa, iyen Fathia Williams.
Pelu ohun to sele nile Mercy naa, awon eniyan n ro pe boya awon mejeeji le tun ero ara won pa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Kò sí nǹkan tó ṣòro tó kí ènìyàn pàdánù ọkọ….. Bimbo Oshin

Kò sí nǹkan tó ṣòro tó kí ènìyàn pàdánù ọkọ….. Bimbo Oshin Ọrẹ Òtítọ́jù Iná ọkọ,aya …