Fayose ta epo ijoba fun awon ara ilu
Gomina Ayodele Fayose ti fihan pe oun laaanu awn ara ilu re o, nipa tita epo petiroolu to wa ni ile ijoba fun won.
Owongogo epo to gba Naijiria kan ko yo Ekiti naa sile.
Fayose wa ni oju oun ko gba a mo, ki awon ni epo ni ile ijoba, ki awon ara ilu wa maa jiya ajelamiloju.
O ni ki won maa ta epo naa ni N145 jala kan (N145 per litre).
O ni ninu ida ogorun 60,000 litres to wa nikawo oun, ki won ta ida ogorin nibe.
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…