Home iroyin Ààrẹ Buhari tọrọ àforíjì lórí epo tó wọn gógó
iroyin - December 25, 2017

Ààrẹ Buhari tọrọ àforíjì lórí epo tó wọn gógó

Aare Muhammadu Buhari toro aforiji lowo awon omo Naijiria lori epo petiro to won gogo. O ni gbogbo awon obayeje pata ti won moomo maa fara ni ara ilu ni owo sinkun ofin ijoba maa te. O ni awon si maa fi won jofin. Aare ni ko si idi pataki kankan to fi ye ki epo won rara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ọlọ́ọ̀pá ATRS yòó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ Èkó dípò SARS

Ọlọ́ọ̀pá ATRS yòó yòó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ Èkó dípò SARS Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé ètò ààbò ìl…