Home Orisirisi Iresi Amosun fi N500 dinwo si ti Ambode
Orisirisi - December 24, 2017

Iresi Amosun fi N500 dinwo si ti Ambode


Bi o tile je pe a ko tii mo eyi to dun ju, o jo pe iresi ti ijoba Ipinle Eko ati Ogun n ta fun awon ara ilu fi eedegbeta naira – N500 – dinwo si ara won.
A gbo pe baagi nla ni Ipinle Eko je egberun mejila naira – N12,000 – nigba ti ti Ogun je egberun mokanla abo – N11,500.
Ijoba Akinwunmi Ambode lo koko bere ogbin iresi pelu ijoba ipinle Kebi, nigba ti Ibikunle mosun naa sese bere tie.
Ohun ti a ko tun ti mo ni boya awon apo iresi naa tobi ju ara won lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…