Home LÁGBO ÀRÍYÁ Eni kan lo mo, awon osere ti adanwo nla ba ni 2017
LÁGBO ÀRÍYÁ - December 23, 2017

Eni kan lo mo, awon osere ti adanwo nla ba ni 2017


Nigba ti odun 2017 je eyi to so eso rere fun opo awon gbajumo osere, ko ri bee fun awon kan o. Lara awon eniyan bee ni Remi Surutu ati Eucharia Anunobi. Awon mejeeji lo padanu omobinrin kookan, ti aye sib a won daro pupo.
Nigba ti Surutu padanu omobinrin, Eucharia padanu omokunrin. Oda omo kan soso ti Olorun tii yonda fun Eucharia niyen. Ohun to tun wa seni laanu nip e arun arunmoleegun (sickle cell) lo pa awon omo mejeeji naa.
Ki Olorun d aero gidi pada fun won.
Oro naa kan akewi pataki, Alagba Lanrewaju Adepoju die. Olorun ko je ki o sofo omo, sugbon aare oju to ba a. Arun naa ti wa lati odun bii marun-un seyin. Sugboon ohun to je ki ti 2017 le ni pe awon omo Naijiria da owo bii milionu meje fun un lati se ise abe ni ile okeere.
Sugbon nigbba ti akewi naa de India, a gbo pe awon gbajue kan kolu u.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò Yìnká Àlàbí O ma se o! Awo̩n ake̩ko̩o̩…