Home iroyin Adajo ju oba alaye si ewon odun meji
iroyin - December 23, 2017

Adajo ju oba alaye si ewon odun meji

Kayeefi nla kan ti sele ni Ipinle Ondo.
Odidi oba alaye ni ile ejo ti ju si ewon odun meji gbako.
Oba naa ni ti Ilu Igburowo ni ijoba ibile Odigbo, ni Ipinle Ondo.
Adajo O. J. Adelegan lo ju oba naa sewon lai boju weyin rara.
Won gbe Oba Akinfesola Adewola lo si ile ejo lori esun pe gbogbo owo ti o n bo si I lowo lati ijoba ibile naa lo n se basubasu.
Awon oba ati ijoye yoku ni agbegbe naa lo gbe Kabiyesi lo ile ejo, lori pe kii fun won lowo to to si won.
Adajo delegan ni loooto, oba alase ni dewola, sugbon ofin ko da eni kan mo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…