Home iroyin Bílíọ̀nù kan owó ilẹ̀ òkèèrè wà fún gbogbo ètò-àbò – Osinbajo
iroyin - December 20, 2017

Bílíọ̀nù kan owó ilẹ̀ òkèèrè wà fún gbogbo ètò-àbò – Osinbajo

Igbakeji Aare Naijiria, Ojogbon Yemi Osinbajo lo n salaye fun awon oniroyin pe ki won ma se je k iawon oloselu kan paro fun won lori oro Naijiria. O ni Bilionu kan owo ile okeeere ti ijoba ya soto fun eto-abo ilu wa fun gbogbo eto-abo Olopaa, Soja ori ile, Soja ori omi, Soja ori ofurufu ati gbogbo awon eleto aabo to ku.
O ni ko si otito kankan ninu oro awon ti won ni Boko Haram nikan ni ijoba apapo ya owo naa soto fun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run

Ìyá Rainbow ṣọjóòbí, ó ní ẹ̀bẹ̀ pàtàkì kan lòun n bẹ Ọlọ́run Ọrẹ Òtítọ́jù Ayẹyẹ ọjọ́ọ̀bì à…